Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

JW LANGUAGE

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW Language (Windows)

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW Language (Windows)

JW Language máa ṣiṣẹ́ lórí àwọn fóònù àti kọ̀ǹpútà yìí:

  • Àwọn kọ̀ǹpútà àtàwọn tablet tó jẹ́ Windows 8.1 sókè

Ó lè má ṣiṣẹ́ lórí àwọn fóònù àti kọ̀ǹpútà yìí:

  • Àwọn kọ̀ǹpútà tó jẹ́ Windows 8.0 sísàlẹ̀

  • Gbogbo fóònù Windows

 

Ọ̀rẹ́ ẹ kan tó mọwọ́ JW Language lè ràn ẹ́ lọ́wọ́. Tó ò bá wá rẹ́ni ràn ẹ́ lọ́wọ́, kọ ọ̀rọ̀ kún fọ́ọ̀mù wa lórí ìkànnì,kó o sì fi ránṣẹ́.