Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

AUGUST 2, 2019
RỌ́ṢÍÀ

A Gbọ́rọ̀ Látẹnu Arákùnrin Dmitriy Mikhaylov

A Gbọ́rọ̀ Látẹnu Arákùnrin Dmitriy Mikhaylov

Arákùnrin Mikhaylov sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe fàṣẹ ọba mú òun láìtọ́, tí wọ́n sì fi òun sátìmọ́lé lóṣù May 2018.