Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Mexico

  • Palacio de Bellas Artes , Mexico City, Mexico​—Wọ́n ń kọ́ni látinú Bíbélì

  • Betania, Chiapas State, Mexico—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé pẹlẹbẹ tó dá lórí Bíbélì ní èdè Tzotzil

  • San Miguel de Allende, Guanajuato State, Mexico​—Wọ́n ń ka ẹsẹ Bíbélì kan tó ń fúnni níṣìírí

Ìsọfúnni Ṣókí—Mexico

  • 132,834,000—Iye àwọn èèyàn
  • 864,738—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 12,706—Iye àwọn ìjọ
  • 155—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

“Ìgbà Wo La Tún Máa Ṣe Àpéjọ Mí ì?”

Kí ló ṣàrà ọ̀tọ̀ nípa àpéjọ àgbègbè kékeré tí wọ́n ṣe ní Mexico City lọ́dún 1932?

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní Mẹ́síkò

Wo ohun tó mú kí àwọn ọ̀dọ́ kan borí oríṣiríṣí ìṣòro kí wọ́n lé ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ Kristẹni.