Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Cambodia

Ìsọfúnni Ṣókí—Cambodia

  • 16,855,000—Iye àwọn èèyàn
  • 1,116—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 17—Iye àwọn ìjọ
  • 15,295—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ìpinnu Tí Mo Ṣe Nígbà Tí Mo Wà ní Kékeré

Ọmọkùnrin kan láti Columbus, ní ìpínlẹ̀ Ohio, lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà pinnu láti kọ́ èdè Cambodian. Kí nìdí? Báwo ló ṣe mú kó yan ohun tó fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe?