Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Ecuador

  • Chambo, Ecuador​—Ẹlẹ́rìí kan ń fún èèyàn ní ìwé pẹlẹbẹ lédè Quichua

Ìsọfúnni Ṣókí—Ecuador

  • 16,939,000—Iye àwọn èèyàn
  • 100,195—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,212—Iye àwọn ìjọ
  • 171—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

A Gbèjà Àwọn Ará Wa Kí Wọ́n Lè Ní Òmìnira Láti Jọ́sìn

Nígbà táwọn alátakò gbéjà ko àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, tí wọn ò sì fún wọn lómìnira láti jọ́sìn ní fàlàlà, àwọn ará gbégbèésẹ̀ ní kíá láti ràn wọ́n lọ́wọ́.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Ecuador