Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Juan Pablo Zermeño: Jèhófà Ti Jẹ́ Káyé Mi Nítumọ̀

Juan Pablo Zermeño: Jèhófà Ti Jẹ́ Káyé Mi Nítumọ̀

Ọ̀pọ̀ àwọn tí ojú wọn rí màbo nígbà tí wọ́n wà lọ́mọdé ló ti ní ìbàlẹ̀ ọkàn báyìí tí ayé wọn sì nítumọ̀ nítorí pe wọ́n pinnu pé Jèhófà ni àwọn máa fi ayé wọn sìn. Ẹ̀ṣẹ́ ni Juan Pablo máa ń kàn tẹ́lẹ̀. Àmọ́, ó pinnu láti fi iṣẹ́ yẹn sílẹ̀, ayé rẹ̀ sì wá nítumọ̀.