Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Abala 1—Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé

Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Abala 1—Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé

Jèhófà jẹ́ ká mọ bó ṣe fẹ́ gba aráyé là. Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Sekaráyà àti Èlísábẹ́tì ti darúgbó, áńgẹ́lì Jèhófà kan sọ fún wọn pé wọ́n máa bí ọmọkùnrin kan tó máa di wòlíì. Bákan náà, Jósẹ́fù àti Màríà ló máa tọ́ Mèsáyà náà dàgbà, wọ́n á sì dáàbò bò ó lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá tó máa fẹ́ pá á ní kékeré.