Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Wọ Ilẹ̀ Kénáánì

Wa àwọn káàdì yìí jáde, kó o sì tò àwòrán àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn nínú ìtàn tó wà ní Jóṣúà orí 2 sí 7 pọ̀ mọ́ àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe tá a sọ nínú amọ̀nà tó wà lára káàdì yìí.