Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÌWÉ ÀJÁKỌ

Bó O Ṣe Lè Kojú Àwọn Ìrora tó Máa Ń Bá Ìgbà Ìbàlágà Rìn

Ìwé àjákọ yìí á ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè kojú àwọn ìṣòro tó máa ń bá ìgbà ìbàlágà rìn.