Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Bíbélì Àfọwọ́kọ

Ìwé Àfọwọ́kọ Àtijọ́ Kan Ṣètìlẹ́yìn fún Lílo Orúkọ Ọlọ́run

Wo ẹ̀rí tó fi hàn pé orúkọ Ọlọ́run wà nínú “Májẹ̀mú Tuntun.”

Ohun Siseyebiye Ti Won Ri Ninu Pantiri

Ajaku orepete Rylands ti Ihin Rere Johanu wa ninu re ni iwe afowoko ti Iwe Mimo Kristeni Lede Giriiki ti ojo re pe ju lo.

Àkájọ Ìwé Àtijọ́ Kan

Lọ́dún 1970, àwọn awalẹ̀pìtàn ṣàwárí àkájọ ìwé kan tí iná ti rà ní agbègbè Ein Gedi, Ísírẹ́lì. Àmọ́, nígbà tí wọ́n fi ẹ̀rọ ìgbàlódé tí wọ́n fi máa ń ṣàyẹ̀wò irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wò ó, ìyẹn 3-D scanner, wọ́n rí ohun tó wà nínú rẹ̀ kà. Kí ni wọ́n rí nínú ẹ̀?

Ohun Tí Kò Jẹ́ Kí Bíbélì Pa Run

Ìwé awọ àti òrépèté làwọn tó kọ Bíbélì àtàwọn tó ṣe àdàkọ rẹ̀ lò. Báwo ni ìwé tọ́jọ́ rẹ̀ ti pẹ́ gan-⁠an yìí ṣe wà títí dòní?

Ǹjẹ́ Àkọsílẹ̀ Bíbélì Nípa Ìgbésí Ayé Jésù Péye?

Ṣàgbéyẹ̀wò àwọn nǹkan tó jóòótọ́ nípa àkọsílẹ̀ tó wà nínu ìwé Ìhìn Rere àtàwọn ìwé àfọwọ́kọ tó pẹ́ jù lọ.