Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú TẸ̀ Ẹ̣́ Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ń tù wá nínú nígbà téèyàn wa bá kú? Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde O Tún Lè Wo JÍ! Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Bíbélì ń tuni nínú, ó ń fúnni ní ìrètí, ó sì ń ṣèrànwọ́ fún àwọn tí èèyàn wọn kú. OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Ṣé Mo Lè Rí Àwọn Ọ̀rọ̀ Tó Máa Tù Mí Nínú Nínú Bíbélì? Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó ti tu àwọn tó ní ìṣòro àti ẹ̀dùn ọkàn nínú. ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀. ILÉ ÌṢỌ́ Tí Ẹnì Kan Tó O Fẹ́ràn Bá Kú, Ṣé Ayé Rẹ Ṣì Lè Dùn? Wo ohun márùn-ún tó o lè ṣe tí ẹnì kan tó o fẹ́ràn bá kú. OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Kí Ni Àjíǹde? Ó lè yà ẹ́ lẹ́nu tó o bá mọ àwọn tí Bíbélì sọ pé Ọlọ́run máa jí dìde. NÍPA WA Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Yorùbá Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/501100047/univ/art/501100047_univ_sqr_xl.jpg mrt àpilẹ̀kọ 54