ILÉ ÌṢỌ́ January 2015 | Ijoba To Maa Fopin Si Iwa Ibaje

Kari aye, awon eeyan gba pe awon eto ti ijoba gbe kale ni awon jegudujera po si ju. Nje o see se ka ni ijoba ti ko ni huwa ibaje?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Iwa Ibaje Inu Ijoba Eeyan

Oro ta a n so yii ti le ju ohun ti opo eeyan n ro.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ijoba Olorun, Ijoba To Bo Lowo Iwa Ibaje

Awon eri mefa to fi han pe Ijoba Olorun bo lowo iwa ibaje.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Bibeli Dahun Gbogbo Ibeere Mi

Igbagbo ti Mayli Gündel ni ninu Olorun mehe nigba ti baba re ku. Bawo ni igbagbo re se soji to fi wa ni ibale okan?

Eyin Oko—E Mu Ki Ile Yin Tura

Idile kan le ma ni isoro jije mimu, sibe ki ara ma tu won.

Nje O Mo?

Awon wo ni “iwefa” ti Bibeli menu kan? Ki nidi tawon oluso aguntan fi maa n ya aguntan soto lara awon ewure laye atijo?

Se Jesu Lo Ye Ka Maa Gbadura Si?

Jesu funra re dahun ibeere yii.

Ohun Ti Bibeli So

Se Olorun lo da awa eeyan abi ara eranko la ti wa?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ǹjẹ́ Bíbélì Sọ̀rọ̀ Nípa Ìgbéyàwó Láàárín Ọkùnrin àti Ọkùnrin Tàbí Láàárín Obìnrin àti Obìnrin?

Ẹni tó dá ìgbéyàwó sílẹ̀ ló yẹ kò mọ̀ béèyàn ṣe lè ní ìgbéyàwó tó wà pẹ́ títí lọ, tó sì láyọ̀.