ILÉ ÌṢỌ́ No. 4 2016 | Bí Ọlọ́run Ṣe Pa—Bíbélì Mọ́

Láti àìmọye ọdún sẹ́yìn, onírúurú nǹkan ló ṣẹlẹ̀ tí ì bá ti pa Bíbélì run tabí yí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ pa dà, àmọ́ Ọlọ́run pa á mọ́. Kí nìdí tí èyí fi gba àfiyèsí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìtàn Tó Ṣe Pàtàkì

Kó sí ìwé tó mú káwọn èèyàn gbé ìgbé ayé tó dáa tó sì ti wà láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Àmọ́ ṣe a lè gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tí Kò Jẹ́ Kí Bíbélì Pa Run

Ìwé awọ àti òrépèté làwọn tó kọ Bíbélì àtàwọn tó ṣe àdàkọ rẹ̀ lò. Báwo ni ìwé tọ́jọ́ rẹ̀ ti pẹ́ gan-⁠an yìí ṣe wà títí dòní?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bíbélì Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Alátakò

Ọ̀pọ̀ olóṣèlú àtàwọn aṣáájú ẹ̀sìn tí gbìyànjú láti mú káwọn èèyàn má ṣe ní Bíbélì, kí wọ́n ṣe ẹ̀dà rẹ̀ tàbí kí wọ́n túmọ̀ rẹ̀. Àmọ́ wọn ò ṣàṣeyọrí.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bíbélì Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Tó Fẹ́ Yí Ọ̀rọ̀ Inú Rẹ̀ Pa Dà

Àwọn aláìdáa kan tí gbìyànjú láti yí ọ̀rọ̀ inú Bíbélì pa dà. Báwo ni àṣírí ìwà àìdáa wọn ṣe tú, tí wọn ò sì ṣàṣèyọrí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìdí Tí Bíbélì Fi Wà Títí Dòní

Ohun tó mú kí ìwé yìí ṣàrà ọ̀tọ̀?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí ló ṣàrà ọ̀tọ̀ nínú bí Jésù ṣe hùwà sáwọn adẹ́tẹ̀? Kí ló lè mú káwọn aṣáájú ẹ̀sìn Júù gbà káwọn kan kọra wọn sílẹ̀?

Ǹjẹ́ Ilẹ̀ Ayé Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìwà Ipá?

Àwọn kan tí ìrànlọ́wọ́ gbà tó mú kó ṣe é ṣe fún wọn láti jáwọ́ pátápátá nínú ìwà ipá. Ohun tó ràn wọ́n lọ́wọ́ lè ran àwọn míì lọ́wọ́.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Mo Ṣàṣìṣe Lọ́pọ̀ Ìgbà àmọ́ Mo Ṣàṣeyọrí

Báwo ni ọ̀gbẹ́ni kan ṣe jáwọ́ nínú àwòrán ìṣekúṣe tó ti di bárakú fún un, tó sì wá ní ìbàlẹ̀ ọkàn?

Àfiwé Tó Dára Jù Lọ Tó O Lè Ṣe

Ẹgbẹgbẹ̀rún ẹ̀yà ìsìn tó ń pe ara wọn ní Kristẹni ló wà, síbẹ̀ ẹ̀kọ́ wọn àti èrò wọn kò dọ́gba rárá. Báwo lo ṣe lè dá èyí tó ń jóòótọ́ mọ̀?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ Ọlọ́run lè lo ètò tó kan láti máa fa àwọn èèyàn wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì Ti Wá?

Ọ̀pọ̀ àwọn tó kọ Bíbélì sọ pé Ọlọ́run ló darí àwọn láti kọ́ ohun táwọn kọ. Kí nìdí?