ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ June 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 12–​September 8, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 23

Jèhófà Gbà Wá Lálejò Sínú Ilé Ẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 12-18, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 24

Má Kúrò Nínú Ilé Jèhófà Láé!

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 19-25, 2024.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Gbọ́ Àdúrà Mi

Kí ló jẹ́ kó dá Marcel Gillet lójú láti kékeré pé Jèhófà ni “Olùgbọ́ àdúrà”?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ṣé “àwọn tí ìyà ń jẹ” (ẹsẹ 5) tàbí “àwọn ọ̀rọ̀ Jèhófà” (ẹsẹ 6) ni gbólóhùn náà “Wàá máa ṣọ́ wọn,” tó wà ní Sáàmù 12:7 ń sọ nípa ẹ̀?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 25

Máa Rántí Pé Jèhófà Ni “Ọlọ́run Alààyè”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 26–​September 1, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 26

Fi Jèhófà Ṣe Àpáta Rẹ

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní September 2-8, 2024.