ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI July–August 2023 ṢÍ GBOGBO Ẹ̀ SÍLẸ̀ PA GBOGBO Ẹ̀ DÉ July 3-9 Fi èyí tó pọ̀ hàn ‘Ẹ Má Ṣe Dí Iṣẹ́ Náà Lọ́wọ́’ ‘À Ń Gbèjà Ìhìn Rere, A sì Fìdí Rẹ̀ Múlẹ̀ Lọ́nà Òfin’ July 10-16 Fi èyí tó pọ̀ hàn Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga July 17-23 Fi èyí tó pọ̀ hàn Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀ July 24-30 Fi èyí tó pọ̀ hàn “Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà” July 31–August 6 Fi èyí tó pọ̀ hàn Ṣé Ó Máa Ń Yá Ẹ Lára Láti Ṣe Iṣẹ́ Tó Dà Bíi Pé Ó Rẹlẹ̀? August 7-13 Fi èyí tó pọ̀ hàn Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba Wọ́n Ń Ṣiṣẹ́ Kára Nítorí Wa August 14-20 Fi èyí tó pọ̀ hàn “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín” O Lè Mú Kí Ayọ̀ Túbọ̀ Wà Nínú Ìdílé Rẹ August 21-27 Fi èyí tó pọ̀ hàn Wọ́n Yááfì Ohun Ìní Wọn fún Jèhófà Àwọn Nǹkan Wo Lo Lè Fi Ṣe Àfojúsùn ní Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Tó Ń Bọ̀? Àkànṣe Ìwàásù Láti Kéde Ìjọba Ọlọ́run Lóṣù September August 28–September 3 Fi èyí tó pọ̀ hàn Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́ Máa Fìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Bíi Ti Jèhófà Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ