Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọdún 1914 Ni Ayé Yí Pa Dà Bìrí

Ọdún 1914 Ni Ayé Yí Pa Dà Bìrí

Bíbélì sọ bí nǹkan ṣe máa rí láyé àti ìwà táwọn èèyàn á máa hù táá jẹ́ ká mọ̀ pé “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” ti bẹ̀rẹ̀. (2 Tímótì 3:1) Jẹ́ ká wo bí àwọn nǹkan yẹn ṣe túbọ̀ hàn kedere láti ọdún 1914.