Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—A Ṣètò Wa Láti Wàásù Ìhìn Rere

Ó ti lé ní ọgọ́rùn-ún (100) ọdún táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ṣètò ara wa láti máa wàásù ìhìn rere. Ọgọ́rọ̀ọ̀rún èdè la fi ń wàásù ìhìn rere yìí ní ilẹ̀ tó ju igba (200) lọ. Kí ló dé tí iṣẹ́ yìí fi ṣe pàtàkì? Báwo la ṣe ń ṣe é tó fi ń kárí ayé? Fídíò yìí jẹ́ ká rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí, bó ṣe ṣàlàyé kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa bá a ṣe ń ṣe iṣẹ́ ìwàásù wa kárí ayé.

 

O Tún Lè Wo

ÀWỌN ÌṢẸ̀LẸ̀ GIDI

Gbogbo Ẹgbẹ́ Àwọn Ará Wa

Báwo ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń fi ìfẹ́ hàn tí wọ́n sì wà níṣọ̀kan nínú ayé tí kò ti sí ìfẹ́ yìí?