Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

Nígbà tí Jésù wà láyé, ẹ̀kọ́ nípa Ìjọba Ọlọ́run ló kọ́ àwọn èèyàn jù lọ. Kí ni Ìjọba Ọlọ́run? Àńfààní wo ló máa ṣe fún ẹ?